[Music] Zlatan – Wake Up

Zlatan – Wake Up (Audio)

Download MP3

The zanku master is back with another street banger.

Music + Lyrics

Ayii

Ayii

Ayii

Wo

Èmi Sọkalẹ

Ibile

Sọkalẹ

Kapachimerimeripako

Ọya when I wake up in the morning (Spellz)

Modupé fi Ọlọrun

It wasn’t really funny

Kinto gba débi

Kinto gbà débi

When I wake up in the morning

Modupé fi Ọlọrun

It wasn’t really funny

Kinto gbà débi

Ọdọ yi ba yọ mi

Shebi adura momsi àti popsi mi

Ma lo yo mi oh

Ọdọ yi ba yọ mi

Shebi adura momsi àti popsi mi

Ma lọ yo mi oh

Kinto ba debi

Kúrò bẹ

Wọ

Them say love na one tin tin

Na so this ilé aiye sef gon bintin

A jo rin nígbà yẹn ni, a’dẹ mọ ni olówó

Ti kpa ma fi àkara fún mẹ koko

Everyday lafin she adura

Ki Jésù ranti wa, ko ma j’awa ni kan ni nepa ma wa ja’na wà

Showers of blessing lẹ’npe

Ojú tí kún palour wa

Tori every time t’ojo ba rọ, o ma leak lati roof wa

And I wan build this legacy, for my family

Before I komot for house, I promise say them go be proud of me

Jésù nìkan mogbọ’kan le, lẹyìn é kòsí ẹlomi

Lati ni iwọ pe, Jesu ni mo pe to dẹ pick call mí

When I wake up in the morning

Modupé f’ore Ọlọ’un

It wasn’t really funny

Kinto ba debi

Kinto ba debi

When I wake up in the morning

Modupé f’ore Ọlọ’un

It wasn’t really funny

Kinto ba debi

(Kinto ba debi, Jonmo)

Ọdọ yi ba debi

Shebi adura momsi àti popsi mi

Ma lo yo mi oh

Ọdọ yi ba debi

Shebi adura momsi àti popsi mi

Ma lọ yo mi

Kinto ba debi

Wọ, èmi re, èmi re

Mo wà d’ẹni tó rà benz

Èmi re, èmi re

Mo wa dẹni tó wà fresh

Èmi re

Ọmọlẹ, ti olùwà gbogo fun

E ni binu, e so fu pe ologo ni, ko filẹ

Mọ hussle Toronto oh

Nínú òtútù, ni nínú orun

Ko le da fun mi

Ki ma bọ, kọ ni “rara ko ki sho’un”

Mọn ti fresh telé telé woni on sho’un

Awọn l’abọsi, Awọn gbeborun

And I wan build this legacy for my family

Before I komot for house I promise say them go be proud of me

Jésù nìkan mogbọ’kan le, lẹyìn é kòsí ẹlomi

Lati ni iwọ pe, Jesu ni mo pe to dẹ pick call mí

Ọdọ yi ba yọ mi

Shebi adura momsi àti popsi mi

Ma lo yo mi oh

Ọdọ yi ba yọ mi

Shebi adura momsi àti popsi mi

Ma lọ yo mi

Kinto ba debi

Spellz

Sweet